HYMN 391

t.H.C 6s8s (FE 414)
"Oluwa Iwo li o ye lati gba ogo, ati
ola ati agbara" - Ifi. 4:111. BABA, Eleda wa,

   Gbo orin iyin wa 

   L'aiye ati l'orun 

   Baba Olubukun 

   lwo l‘ogo ati iyin 

   Ope, ati ola ye fun.


2. Wo Olorun Omo 

   T’O ku lati gba wa 

   Enit‘O ji dide

   Ti O si goke lo 

   Iwo l'ogo, ati iyin

   Ope, ati ola ye fun.


3. Si O Emi Mimo 

   Ni a korin iyin 

   Iwo t’o f’imole 

   lye si okan wa

   Iwo l’ogo, ati iyin 

   Ope, ati ola ye fun.


4. Mimo, Mimo, Mimo 

   N‘iyin Metalokan 

   L’aiye ati l’orun

   L'a o ma korin pe

   lwo l’ogo, ati iyin 

   Ope, ati ola ye fun. Amin

English »

Update Hymn