HYMN 395

C.M.S.283 H.C 263 L.M (FE 418) 
“Nibe I'OIuwa gbe pase ibukun, 
ani iye lailai“ - Ps. 133:31. BABA orun jinle ‘fe Re 

   L’o wa Oludande fun wa

   A wole niwaju ‘te Re 

   Nawo dariji Re si wa.


2. Omo Baba, t'O d‘Enia 

   Woli, Alufa, Oluwa

   A wole niwaju 'te Re 

   Nawo igbala Re si wa


3. Emi at’aiyeraiye lai 

   Emi ti nji oku dide

   A wole niwaju ‘te Re 

   Nawo isoji Re si wa.


4. Jehovah, Baba, Omo, Emi 

   'Yanu ‘jinle Metalokun 

   A wole niwaju 'te Re 

   Nawo emi ye re si wa. Amin

English »

Update Hymn