HYMN 398

H.C 267 6s (FE 421)
“Oro Re ni fitila si mi lese, ati imole 
si ipa ona mi” - Ps. 119:1051. JESU, oro Re ye 

   O si nto sise wa

   Enit’ o ba gbagbo 

   Y‘o l'ayo on ‘mole.


2. Nigba' ota sunmo wa 

   Oro Re l‘odi wa

   Oro itunu ni

   lko igbala ni.


3. B'igbi at'okunkun 

   Tile bo wa mole 

   Mole re y'o to wa 

   Y’o si dabobo wa.


4. Tani le so ayo 

   T’o le ka isura 

   Ti oro Re nfi fun 

   Okan onirele?


5. Oro anu, o nfi 

   Lera fun alaye 

   Oro iye, o nfi 

   ltunu f'eni nku.


6. Awa iba le mo 

   Eko ti o nkoni

   Ki a ba le fe O 

   K'a si le sunmo O. Amin

English »

Update Hymn