HYMN 400

(FE 423)
Kemble’s Psl 46 t.H.C 342. L.M
“Olorun li abo wa ati agbara” - Ps 46:1


1. OLORUN l’abo eni Re

   Nigba iji iponju de

   K‘a wa to se aroye wa

   A! sa wo t’on t’iranwo Re.


2. B’agbami riru mbu soke 

   Okan wa mbe l’alafia 

   Nigb’ orile at’etido

   Ba njaya riru omi na.


3. lwe owo ni, oro re

   Kawo ibinu fufu wa

   Oro Re m’alafia wa

   O f'ilera f’okan are. Amin

English »

Update Hymn