HYMN 403

S.S 263 (FE 426)
"Ro mo Bibeli” - Ps. 119:105


1. RO mo Bibeli b'a gb’awon nkan 'yoku

   Ma so ilana‘re t’o sowon nu

   Ihin re nji gbogbo okan ti ntogbe 

   Ileri re nso oku d‘alaye.

Egbe: Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!

      Ro mo Bibeli! mole f ’ese wa.


2. Ro mo Bibeli! Oro ‘yebiye yi 

   O nfi ‘ye ainipekun f’ araiye 

   O ni ‘ye ainipekun f‘araiye

   O ni 'ye lori ju b‘eda ti ro lo 

   Wa ibukun Re nigba t’a le ri! 

Egbe: Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!...


3. Fitila f’eniti o ti sako lo 

   Amona fun Odo ti 'ba subu 

   Reti elese t’aiye re ti baje 

   Opa f'agba, Iwe didara julo!

Egbe: Ro mo Bibeli Ro ma Bibeli!

      Ro mo Bibeli! mole f ’ese wa. Amin

English »

Update Hymn