HYMN 406

t.Y.M.H.B.813 (FE 429) 
"Bo sarin keke abe Kerubu" - Eze.10:21. EGBE kerubu ti ye

   So fun mi lekan si

   Jesu Kristi l’Oba Ogo 

   Olugbala l’Oba lye 

   Egbe kerubu l’Egbe lye 

   Egbe Kerubu ti ye.

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu 

      Egbe Kerubu ti ye.


2. Egbe Serafu ti ye

   E f’ogo fun baba

   T’o mu wa ri ojo oni 

   Fi ola fun Baba loke 

   Egbe Serafu l’Egbe lye 

   Egbe Serafu ti ye.

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu

      Egbe Serafu ti ye.


3. Egbe kerubu ti ye

   E so fun mi ki ngbo 

   Jesu Kristi Olusegun 

   Olusegun l'Oba lye 

   Egbe kerubu I’Egbe lye 

   Egbe Kerubu ti ye. 

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu

      Egbe Kerubu ti ye.


4. Egbe Serafu ti ye

   T’o mo ti Krist’ nikan 

   Jesu t'o wa niwaju wa 

   Olugbala, Balogun wa 

   Egbe Serafu l‘Egbe lye 

   Egbe Serafu ti ye. 

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu

      Egbe Serafu ti ye.


5. Egbe kerubu ti ye

   Oba lyanu ni;

   Jesu Kristi, Balogun wa,

   Obangiji l’Oba iye 

   Egbe kerubu l’Egbe lye. 

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu

      Egbe Kerubu ti ye.


6. Egbe Serafu ti ye

   Egbe Iyanu ni 

   “Olubukun I’Enit‘ o mbo 

   Li oruko Oluwa wa

   Ogo ni fun Baba loke 

   Ogo fun Metalokan. 

Egbe: Iyanu, Iyanu, Iyanu

      Egbe Serafu ti ye. Amin

English »

Update Hymn