HYMN 413

(FE 436) C.M.S 586 S. 6s. P.M 
"Enikeni ti o ba pe poruko Oluwa 
a o gba a la" - Joeli 2:321. MA koja mi, Olugbala 

   Gbo adura mi

   Gbati lwo ba np'elomiran 

   Mase koja mi!

Egbe: Jesu! Jesu! Gbo adura mi! 

      Gbat'lwo ba np’elomiran

      Mase koja mi.


2. N'ite anu je k‘emi ri, 

   ltura didun

   Teduntedun ni mo wole

   Jo ran mi lowo.

Egbe: Jesu! Jesu!...


3. N’igbekele itoye Re 

   L'em’o w’oju Re

   Wo ‘banuje okan mi san 

   F‘ife re gba mi.

Egbe: Jesu! Jesu!...


4. 'Wo orisun itunu mi

   Ju ye fun mi lo

   Tani mo ni l'aiye l’orun 

   Bikose lwo?

Egbe: Jesu! Jesu! Gbo adura mi! 

      Gbat'lwo ba np’elomiran

      Mase koja mi. Amin

English »

Update Hymn