HYMN 417

C.M.S 530 C.H. t. H.C 311 C. M 
(FE 440)
“We mi nu kuro ninu ese mi"
- PS.51:21. OLUWA mo de’bi te Re 

   Nibiti anu po

   Mo fe dariji ese mi

   K'o mu okan mi da.


2. Oluwa, ko ye k’emi so 

   Ohun ti mba bere

   O ti mo k’emi to bere 

   Ohun ti emi fe.


3. Oluwa mo toro anu 

   Eyiyi l’opin na

   Oluwa, anu l’o ye mi 

   Je ki anu Re wa. Amin

English »

Update Hymn