HYMN 420

(FE 443) C.M.S 538. H.C 266 L.M 
'Gbo li orun ibugbe Ee gbo, ki o si dariji"
- 1 Oba 8:301. PASE ‘bukun Re t’oke wa 

   Olorun, s’ara ljo yi

   Fi ife ti Baba wo wa

   Ghat‘ a f‘eru gboju s’oke.


2. Pase ibukun Re, Jesu 

   K'a le se omo ehin Re 

   Soro ipa s’okan gbogbo 

   So f 'alailera, tele mi.


3. Pase ‘bukun l’akoko yi

   Emi oto, kun ibi yi

   F'agbara iwosan Re kun

   At'ore-ofe isoji. Amin

English »

Update Hymn