HYMN 428

C.M.S 535 C.H. 411 t.S. 672. S.M
(FE 451)
"E je ki afi igboiya wa si ibi ite ore-ofe"
- Heb.4:16
1. SA wo ite anu! 

   Oro Re pe mi wa, 

   Nibe Jesu f’oju ‘re han 

   Lati gbo adura.


2. Eje etutu ni,

   Ti a ti ta sile

   Pese ebe t’o le bori 

   F’awon t’o nt'Olorun.


3. lfe Re je fun mi 

   Ju bi mo ti fe lo

   A ma fun enti'o bere 

   Ju bi nwon ti nfe Io.


4. Fun wa l’aworan Re 

   At'oju rere Re

   Jeki nle sin O nihinyi

   Ki mba le ba O gbe. Amin

English »

Update Hymn