HYMN 429

C.M.S 532 t.H.C 500 C.M (FE 452) 
“Iwo ni se ibujoko apata mi" - Ps.71:31. OLUWA, 'Wo ki o si gba

   Eni osi bi emi 

   K’emi le sunmo ite Re 

   Ki nke Abba, Baba.


2. Jesu, jowo fi oro Re, 

   S'okunkun mi d’osan 

   Ki gbogbo ayo tun pada 

   Ti mo f'ese gbon nu.


3. Oluwa, mo f’iyanu sin, 

   Ore Re tobi ju

   Pa mi mo ninu ife Re 

   K'emi ma d’ese mo. Amin

English »

Update Hymn