HYMN 430

C.M.S 547 t.H.C 299 C.M. (FE 453)
"Oro mi ki yio pada sodo mi lofo"
 - Isa. 55:111. OLORUN, a so oro Re 

   Bi 'rugbin l‘or‘ile 

   Je k'iri orun se sile 

   K'o mu ipa re wa.


2. K'ota Kristi on enia 

   Muse se sa 'rugbin na 

   K’o f'irin mule l'okan wa 

   K'o dagba ni ife.


3. Ma je ki aniyan aiye

   Bi oro on ayo 

   Tabi ijona, on iji 

   Run lrugbin orun. Amin

English »

Update Hymn