HYMN 431

Tune: C.M.S 491 H.C
215 C&F 3.Y.L.C 88 6s.5s (FE 455) 
“Maa wi nitori ti iranse re ngbo"
- 1Sam.3:91. BA mi soro, Jesu 

   Bi mo ti duro

   Fi okan mi le ‘le 

   Ninu ireti.


2. Ba mi soro Baba 

   Ni wakati yi

   Je ki nri oju Re 

   Nin‘olanla Re.


3. Oro ti O ba so 

   'Oro iye ni 

   Onje orun

   Ma bo mi titi.


4. Tire l’ohun gbogbo 

   Nki si se t'emi

   Ayo ni mo fi wi 

   Pe, Tire l'emi.


5. Fun mi ni imo na 

   T'ise ogo Re

   Mu gbogbo ileri

   Re se s’ara mi. Amin

English »

Update Hymn