HYMN 433

(FE 457)1. OLUWA f‘ise ran mi, Alleluya

   Emi yio je ‘se na fun O

   O wa ninu oro Re, Alleluya

   Wo Jesu nikansoso k'o ye.

Egbe: Wo k‘o ye ara mi ye
 
      Bojuwo Jesu k'o ye,

      Ise l'a toke wa ni Alleluya 

      E jek'a wo Jesu k’a si ye.


2. Ise na kun fun ife, Alleluya 

   Fun enyin era ilu Eko, 

   Ise lat‘oke wa ni Alleluya 

   At’awon t’o wa n'ilu oke.

Egbe: Wo k‘o ye ara mi ye...


3. Gbogbo Egbe agbaiye, Alleluya 

   Jesu nke tantan wipe ma bo 

   Igbala l'ofe d’ode, Alleluya

   Jek‘ajuba Jesu k‘a si ye. 

Egbe: Wo k‘o ye ara mi ye...


4. Jesu Olugbala wa, Alleluya 

   A f'ogo f'oruko Mimo Re 

   Fun idasi wa loni, Alleluya 

   lyin fun Metalokan lailai. 

Egbe: Wo k‘o ye ara mi ye...


5. Kerubu on Serafu, Alleluya 

   E ja titi d’opin emi nyin; 

   K'a le gba ade iye, Alleluya 

   Lodo Baba loke lohun.

Egbe: Wo k‘o ye ara mi ye
 
      Bojuwo Jesu k'o ye,

      Ise l'a toke wa ni Alleluya 

      E jek'a wo Jesu k’a si ye. Amin

English »

Update Hymn