HYMN 434

(FE 458)1. GB‘ALAFlA mba mi lo b'isan odo 

   ‘Gba banuje nyi bi igbi

   Ohunkohun to de ‘Wo si ti ko mi pe 

   O dara, o dara f'okan mi.

Egbe: O dara, o dara, f 'okan mi, 

      O dara, o dara, f ‘okan mi.


2. B'esu ngbe tasi re, t' idanwo si de 

   K‘ero yi leke l’okan mi,

   Pe Kristi ti mo gbogbo ailera mi

   O t'eje Re sile f‘okan mi.

Egbe: O dara, o dara...


3. Ese ti mo da, si ero to logo yi, 

   Gbogbo ese mi laiku ‘kan

   A kan m‘agbelebu, emi ko ru mo 

   Yin Oluwa, yin Oluwa okan mi.

Egbe: O dara, o dara...


4. Ki Kristi je t’emi ni gbogb’ojo aiye mi, 

   B’odo Jordan san lori mi

   Ko si ‘rora mo, ni kiku ni yiye 

   ‘Wo yio f'alafia fun okan mi. 

Egbe: O dara, o dara...


5. Oluwa, Iwo ni awa nduro de 

   Isa oku ki o j'opin wa

   lpe Angeli, ohun Oluwa wa 

   Ni ireti isimi f'okan mi.

Egbe: O dara, o dara, f 'okan mi, 

      O dara, o dara, f ‘okan mi. Amin

English »

Update Hymn