HYMN 44

(FE 61) C.M.S 27, o.t H.C 16, L.M
“Ni ijo mefa ni iwo o sise" - Eks. 20:91. OJO isimi Olorun

   Ojo ti o dara julo

   Ti Oluwa ti fun wa 

   K’awa ko simi ninu re.


2. ljo mefa l‘O fi fun wa 

   K‘a fi se ise wa gbogbo 

   Sugbon ojo keje yato 

   Ojo 'simi Olorun ni.


3. K'a fi ‘se asan wa,sile 

   Ti awa nse n’ijo mefa 

   Mimo ni ise ti oni

   Ti Olorun Oluwa wa.


4. A pada de nisisyi 

   Ninu ile Olorun wa 

  Je k'a korin didun si i 

  Li owuro ojo oni.


5. Ni kutukutu ‘jo keje

   Ni ojo isimi mimo 

   Je k'a jumo korin didun 

   Je k'a si jumo gbadura. Amin

English »

Update Hymn