HYMN 445

t.H.C 153 8s (FE 469)
“Tani Olorun bi Iwo, ti o ndari aise
dede ji" - Mik. 7:181. OLORUN Iyanu ona kan 

   Ti o da bi Tire ko si 

   Gbogb’ogo ore-ofe Re 

   L’o farahan bi Olorun.

Egbe: Tal’Olorun ti ndariji 

      Ore tal’o po bi Tire?


2. N’iyanu at’ayo l’agba 

   Idariji Olorun wa 

   ‘Dariji f’ese t’o tobi 

   T’a f’eje Jesu s’edidi.

Egbe: Tal’Olorun ti ndariji...

 
3. Je ki ore-ofe re yi 

   Ife iyanu nla Re yi

   K’o f’iyin kun gbogbo aiye

   Pelu egbe Angel l’oke.

Egbe: Tal’Olorun ti ndariji 

      Ore tal’o po bi Tire? Amin

English »

Update Hymn