HYMN 447

H.C. 292. t.H.C 483
(2nd Tune) C.M. (FE 471)
"Oluwa ni yio ma se Olorun mi"
- Gen. 28:211. BABA, b'ife Re ni, lati 

   Du mi l’ohun aiye 

   Sa je ki adura mi yi 

   Goke de ite re.


2. F'okan tutu, t’ope fun mi 

   Gba mi lowo kikun

   Fun mi n‘ibukun or-ofe 

   Si je ki nwa fun O.


3. K'ero yi pe, Wo ni temi 

   Ma ba mi lo l'aiye

   Pelu mi Iona ajo mi

   Si ba mi d‘opin re. Amin

English »

Update Hymn