HYMN 450

H.C. 290 (FE 475)
"Ninu ile baba mi, opolopo ibugbe 
Ii o wa” - John 14:21. ‘Gba mo le ka oye mi re

   Ni ibugbe l‘oke

   Mo dagbere f ’eru gbogbo 

   Mo n’omije mi nu.


2. B’aiye koju s’okan mi 

   T’a nso oko si

   Ghana mo le rin Satani 

   Ki nsi jeju k’aiye.


3. K’aniyandcb’ilctmorni
 
   K’iji banuje ja

   Ki nsa de ‘le alafia 

   Olorun, gbogbo mi.


4. Nibe lokan mi y’o luwe 

   N’nu okun isimi

   Ko si wahala t’o le de 

   S’ibale aiya mi. Amin

English »

Update Hymn