HYMN 454

K. 117 .t.H.C. 320 C.M (FE 480) 
"O si pe oruko ibe na ni
Jehovah Jire" - Gen.22:141. KO to k'awon mimo beru

   Ki nwon so ‘reti nu

   ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, 

   Olugbala y’o de.

Egbe: Ka d'amure lati jagun

      Ka d'amure lati jagun

      Ka d'amure e

      Ka d'amure e

      Ka d'amure lati jagun.


2. Nigbati Abraha mu obe 

   Olorun ni ‘Duro" 

   Agbo ti o wa lohun ni 

  Y'o dipo omo na.

Egbe: Ka d'amure lati jagun...


3. ‘Gba Jona ri sinu omi

   Ko ro lati yo mo 

   Sugbon Olorun ran eje 

   T'o gbe lo s’ebute.

Egbe: Ka d'amure lati jagun...


4. B'iru ipa at‘ife yi

   Ti pio l'oro Re to 

   Emi ba ma k‘aniyan mi 

   Le Oluwa lowo.

Egbe: Ka d'amure lati jagun...


5. E duro de iranwo Re 

   B'o tile pe, duro

   B'ileri na tile fa ‘le

   Sugbon ko le pe de.

Egbe: Ka d'amure lati jagun

      Ka d'amure lati jagun

      Ka d'amure e

      Ka d'amure e

      Ka d'amure lati jagun. Amin

English »

Update Hymn