HYMN 455

K.117 t.H.C 320 C.M (FE 480)
"O si pe oruko ibe na ni Jehovah-Jire"
- Gen.22:14 11. KO to k’awon mimo beru 

   Ki nwon so ‘reti nu

   ‘Gba nwon ko reti ‘ranwo Re, 

   Olugbala y’o de.

Egbe: Jesu mbo (3) 

      Enyin Omo ogun, 

      E damure giri.


2. Nigbati Abram mu obe 

   Olorun ni "Duro” 

   Agbo ti o wa lohun ni 

   Y‘o dipo omo na.

Egbe: Jesu mbo...


3. ‘Gba Jona ri sinu omi 

   Ko ro lati yo mo 

   Sugbon Olorun ran eje 

   To gbe lo s’ebute. 

Egbe: Jesu mbo...


4. B'iru ipa at'ife yi
 
   Ti po l'oro Re to 

   Emi ba ma k'aniyan mi 

   Le Oluwa lowo.

Egbe: Jesu mbo...


5. E duro de iranwo Re 

   B’o tile pe, duro

   B’ileri na tile fa ‘le

   Sugbon ko le pe de.

Egbe: Jesu mbo (3) 

      Enyin Omo ogun, 

      E damure giri. Amin

English »

Update Hymn