HYMN 456

H.C 301 D. 7s 6s (FE 481)
Nisale Ii apa aiyeraiye wa”
- Deut. 33: 271. LAIFOIYA l’apa Jesu

   L’aifoiya l’aiye Re,

   Labe ojij’ ife Re 

   L’okan mi o simi

   Gbo! ohun Angeli ni, 

   Orin won d’eti mi, 

   Lati papa ogo wa, 

   Lati okun Jaspi

   Laifoiya l’apa Jesu, 

   Laifoiya l’aiye Re,

   L‘abe ojij’ife Re, 

   L'okan mi o simi.


2. Laifoiya l’apa Jesu

   Mo bo low’aniyan,

   Mo bo lowo idanwo, 

   Ese ko ‘ipa mo,

   Mo bo Iowo 'banuje 

   Mo bo lowo eru,

   O ku idanwo die!

   O k'omije die!

   Laifoiya lapa Jesu, laifoiya laiye Re, 

   L'abe ojij'ife Re, L'okan mi o si mi.


3. Jesu, abo okan mi, 

   Jesu ti ku fun mi

   Apata aiyeraiye 

  L’emi o gbekele

  Nihin l'emi o duro 

  Tit’ oru y’o koja

  Titi ngo fi r‘imole 

  Ni ebute ogo

  Laifoiya lapa Jesu, laifoiya laiye Re, 

  L'abe ojij'ife Re, L'okan mi o si mi. Amin

English »

Update Hymn