HYMN 458

S.21 P.M (FE 483) 
“Awon omo kiniun a ma se alaini, 
ebi a si ma pa won.. awon ti nwa 
Oluwa ki yio se alaini” - PS.34:10
1. LI onakona, “Oluwa y’o pese’

   O le s’ais’ona mi, o le s’aise tire 

   Sugbon lona ‘ra Re, li On o pese!


2. Lakoko to ye, “Oluwa y’o pese’ 

   O Ie s’aise temi, o le s’ aise tire 

   Lakoko t’ara Re, li On o pese!


3. Ma beru, ‘tori “Oluwa y’o pese", 

   Eyi n’ileri Re, ko s’oro ti O so, 

   Ti si yipada, ‘Oluwa o pese.


4. Yan lo l'aibikita, okun y'o pinya

   O f‘orin isegun se ona re logo,

   A o jumo gberin, ‘Oluwa y’o pese. Amin

English »

Update Hymn