HYMN 460

t.H.C 155 S.M (FE 485)
"Oluwa, iwo ni mo gbeke mi le mase je
ki oju ti mi lae, gba mi ninu odod Re"
-  Ps.31:1
1.  MO f'emi mi sabe 

Itoju Re Jesu

'Wo  ko Jo mi l'ainireti

"Wo l'Olorun Ife.


2.  ‘Wo ni mo gbekele 

‘Wo ni mo f’ara ti 

Rere at’Otito ni O 

Eyi t'O se l'o to.


3.  Ohun t’o wu k’o de 

Ife Re ni nwon nse

Mo f’ori pamo s'aiya Re, 

Nko foiya iji yi.


4.  B’ibi tab‘ire de, 

Y'o dara fun mi sa!

Ki nsa ni O l‘ohun gbogbo 

Ohun gbogbo n'nu Re.  Amin

English »

Update Hymn