HYMN 466

H.C 300 8s 4s (FE 491) 
“Alafia ki o wa bi Alafia ni”
- 2Kings. 4:261. NIPA ife Olugbala

   Ki y’o si nkan

   Ojurere Re ki pada

   Ki y’o si nkan 

   Owo n l’eje t’o wo wa san 

   Pipe l’edidi or’ofe

   Agbara l’owo o gba ni 

   Ko le si nkan.


2. Bi a wa ninu iponju

   Ki y’o si nkan 

   Igbala kikun ni tiwa

   Ki y’o si nkan 

   Igbekele Olorun dun 

   Gbigbe inu Krist’ l’ere 

   Emi si nso wa di mimo 

   Ko le si nkan.


3. Ojo ola yio dara

   Ki y’o si nkan

   Gbagbo le korin n’iponju

   Ki y’o si nkan

   A gbekele ‘fe Baba wa

   Jesu nfun wa l’ohun gbogbo 

   Ni yiye tabi ni kiku 

   Ko le si bkan. Amin

English »

Update Hymn