HYMN 467

H.C. 398 t.H.C 120 8s. 7s (FE 492) 
“Ohun ogo li a nso ni tire, ilu Olorun”
 - Ps. 87:31. OHUN ago Re l’a nrohin 

   Sion, ti Olorun wa

   Oro enit’ a ko le ye 

   Se o ye fun ‘bugbe Re 

   L’ori apat’aiyeraiye 

   Kini le mi ‘simi re?

   A f’odi ‘gbala yi o ka 
  
   K’o le ma rin ota re.


2. Wo! ipado omi iye 

   Nt’ife Olorun sun wa

   O to fun gbogbo omo Re 

   Eru aini ko si mo

   Tal’o le re ‘gba odo na 

   Ba nsan t’o le pongbe re 

   Or’ofe Olodumare

   Ki ye lat’irandiran.


3. Ara Sion alabukun

   T’o f’eje Oluwa we

  Jesu ti nwon ti ngbekele 

  So won d'oba woli Re

  Sisa l’ohun afe aiye

  Pelu ago asan re

  Isura toto at'ayo 

  Kik'omo Sion l'o mo. Amin

English »

Update Hymn