HYMN 476

(FE 502) Tune: "Egbe Aladura mura" 
“Oluwa yara gba wa" - Ps.70:11. OLUWA Olorun gba wa, lowo iku ojiji 

   Olorun Olugbala wa iwo l’awa gbekele 

   Oluwa dabobo wa lowo aje. at’oso

   Ise po t’awa yio se nitorina da wa si.

Egbe: Da wa si, da wa si ) 2ce

      Ise po t'awa yio se 

      Nitorina da wa si.2. Olorun Olodumare, gba wa 

   low’ ajak’arun 

   Ma je ki emi buburu, le wole 

   to Serafu 

   Oluwa dabobo wa, lowo aje, at’oso

   Ise po t’aw yio se, nitorina da wa si.

Egbe: Da wa si, da wa si...


3. Emi Mimo ko pelu wa l’okunrin at’obinrin 

   Ka le je ti Kristi Oluwa, larin odun t’a wa yi 

   Oluwa dabobo wa, lowo aje, at‘oso 

   Ise po t’awa yio se, nitorina da wa si.

Egbe: Da wa si, da wa si ) 2ce

      Ise po t'awa yio se 

      Nitorina da wa si. Amin

English »

Update Hymn