HYMN 483

C.M.S 430 H.C 432 10 s (FE 509)
"Nigbagbogbo ni enyin sa ni talaka
lodo nyin" - Mark 14:71. MO nlo, talaka mi mbe lodo

   E lo ma sore fun won b’e ti nfe.


2. Eyi ni ogun t‘Olugbala wa, 

   Fi sile f'awon Tire k'o to lo.


3. Wura on jufu ko, otosi ni

   K’a ma ran won lowo nitori Re.


4. Eru nla ko ogun t’o l’oro ni 

   Ti nf'ilopo ‘bukun f’eni' ntore.


5. T'iwa k’ise na bi? L’ojude wa, 

   Ko ni talaka at‘asagbe wa?


6. Ohun irora awon t‘iya nje

   Ko ha nke si wa lati f‘anu han?


7. Okan t'o gb‘ogbe, okan ti nsise 

   Ekun opo at'alaini baba!


8. On t'o f'ara Re fun wa, si ti fi 

   Etu orun f‘awa iranse Re.


9. Ko s‘otosi kan ti ko le sajo 

   F'eni tosi ju lo agbara ni.


10. Isin mimo ailabawon l‘eyi

    Ti Baba mbere lowo gbogbo wa. Amin

English »

Update Hymn