HYMN 49

S. 230 7S 6s (FE 66)
"Gbo adura mi Oluwa si jeki igbe mi 
ki o wa sodo Re" - Ps. 102:11. OLUGBALA gbohun mi, 

   Gbohun mi, gbohun mi, 

   Mo wa sodo Re gba mi 

   Nibi agbelebu, 

   Emi se, sugbon O ku 

   lwo ku, lwo ku,

   Fi anu Re pa mi mo,

   Nibi agbelebu.

Egbe: Oluwa jo gba mi

      Nk'y'o bi O ninu mo! 

      Alabukun gba mi 

      Nibi Agbelebu.


2. Tori ki ng' ma ba segbe 

   Ngo bebe! ngo bebe! 

   lwo li ona iye

   Nibi agbelebu

   Ore-Ofe Re t'a gba 

   Lofe ni! Lofe ni! 

   F’oju anu Re wo mi, 

   Nibi agbelebu. 

Egbe: Oluwa jo gba mi...


3. F'eje mimo re we mi 

   Fi we mi,! Fi we me!

   Ri mi sinu ibu Re,

   Nibi agbelebu,

   Gbagbo l'o le fun wa ni, 

   'Dariji !, Dariji !

   Mo fi f'igbagbo ro mo O.

Egbe: Oluwa jo gba mi... Amin

English »

Update Hymn