HYMN 493

C.M.S 510 t.H.C 336 11s (FE 516)
"Nibe ni eni-nuburu siwo iyonilenu, 
nibe eni-ara wa ninu isimi" - Jobu 3:171. ISlMl wa l'orun, ko si l'aiye yi

   Emi o se kun, gbati yonu ba de 

   Simi, okan mi, eyikeyi t‘o de

   O din ajo mi ku, o mu k'ile ya.


2. Ko to fun mi, ki nma simi nihinyi 

   Ki nsi ma kole mi ninu aiye yi

   Ongbe ilu t'a ko f'owo ko ngbe mi

   Mo nreti aiye ti ese ko baje.


3. Egun esusu le ma hu yi mi ka 

   Sugbon emi ko Je gbara le aiye

   Emi ko wa isimi kan ni aiye

   Tit'eni o fi simi laiya Jesu mi.


4. 'Yono Je damu sugbon ko le pa mi 

   Oju 'fe Jesu le so 'yonu d'erin

   Erin Re le so ekun wa di ayo

   B'igba t'efufu fe ojo sisu lo. Amin

English »

Update Hymn