HYMN 498

(FE 525)1. ALA kan ti mo la loru yi 

   Michael lo sokale wa

   Mo ri pe o fo‘tegun esu 

   Ogo ni fun Jesu li orun

Egbe: Ka ba gbogbo Angeli sokan 

      lati korin

      To fi segun goke re orun 

      Lehin t'O ti bori esu

      Lehin t'O ti bori esu. 


2. Kerubu pelu Serafu

   E mura ke damure nyin

   lse Oluwa l’awa nje

   Awa ki yio beru enikan

Egbe: Ka ba gbogbo Angeli...


3. Aki gbogb’ awon Leader wa 

   T‘o wa ba wa se Ajodun

   Ki Olorun ko mese nyin duro 

   Lati gba ‘de iye li orun.

Egbe: Ka ba gbogbo Angeli...


4. A ki Mose Orimolade

   Fun ‘se nla t’o se l’arin wa

   K’Olorun ko busi ise re

   Ade Ogo yio je tire.

Egbe: Ka ba gbogbo Angeli sokan 

      lati korin

      To fi segun goke re orun 

      Lehin t'O ti bori esu

      Lehin t'O ti bori esu. Amin

English »

Update Hymn