HYMN 499

(FE 527)
Tune: Aje lasan ni
“Emi yio so o di Ogo Aiyeraiye”
 - Isa.60:151. B'IKU ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa.


2. B'aiye ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa.


3. B'esu ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa.


4. B'aje ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa.


5. B'oso ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa.


6. B'ota ba ngbogun s'omo Ajasegun

Egbe: E ma foiya,

      E ja bi omo igbala mi,

      E t'esu pa. Amin

English »

Update Hymn