HYMN 51

SS & S. 390 (FE 68)
"Eniti o ba to mi wa" ‐ Matt. 11:281. Jesu nfe gba elese

   Kede re fun gbogbo eda, 

   T’o yapa ona run le,

   At’ awon ti njafara.

Egbe: Ko o Iorin ko si tun ko 

      Kristi ngba gbogbo elese 

      Je ki 'hin na daju pe 

      Kristi ngba gbogbo elese.


2. Wa y’o o fun o ni ‘simi 

   Gba A gbo, oro re ni:

   Y'o gb’elese to buru 

   Krisiti ngba gbogbo elese. 

Egbe: Ko o Iorin...


3. Okan mi ko lebi mo, 

   Mo mo niwaju ofin, 

   Enit’o we mi mo

   Ti san gbogbo gbese mi.

Egbe: Ko o Iorin...


4. Kristi ngba gbogbo'elese 

   An' emi to d‘ese ju, 

   T'a we mo patapata

   Y'o ba wo ‘joba orun.

Egbe: Ko o Iorin... Amin 

English »

Update Hymn