HYMN 510

Ohun Orin: IWO MBO OLUWA1. ASEGUN awon esu

   Asegun awon iku 

   Oluwa si ti jona

   Adupe lowo Baba.

Egbe: A segun, A segun, 

      Olusegun ti de na

      K’awon aje p'agan mo

      Ajesegun mbe nihin.


2. A segun koto iku

   A segun koto esu 

  Oluwa si di won pa 

   A dupe lowo Baba.

Egbe: A segun, A segun...


3. A segun ofa iku

   A segun ofa esu 

   Oluwa so won d’ofo 

   A dupe lowo Baba. 

Egbe: A segun, A segun...


4. Esu ko le l’agbara 

   Lori Egbe Mimo yi 

   Aje, oso, sanponna 

   Di temole l’ese wa.

Egbe: A segun, A segun...


5. Jah yio ma s‘Alabo wa 

   Lowo emi buburu 

   Michael Balogun wa 

   Tid’ oju esu bole.

Egbe: A segun, A segun...


6. Ajiagommon Bussawuu 

   Ajiagommon Buttari 

   Omo Mimo ti segun,

   A dupe lowo Baba.

Egbe: A segun, A segun...


7. Ayo ni fun wa loni 

   Lahhollah, e bu s‘ayo 

   Jesu Balogun nla wa

   Ti segun iku fun wa.

Egbe: A segun, A segun, 

      Olusegun ti de na

      K’awon aje p'agan mo

      Ajesegun mbe nihin. Amin

English »

Update Hymn