HYMN 524

C.M.S 342 H.C 300 S.M 
2nd Ed (FE 549)
"Nigbati nwon ko si rti ti nwon o san, 
tinutintu Ii o dariji awon mejeji"
 ‐ Luke.7:42
1. O FUN mi l’edidi 

   Gbese nla ti mo je

   B’o ti fun mi, o si rerin 

   Pe, Mase gbagbe mi’.


2. O fun mi l’edidi

   O san igbese na

   B’oti funmi, O si rerin 

   Wipe, Ma ranti mi!


3. Ngo p’edidi na mo 

   B’igbesi tile tan

   O nso ife enit’ o san 

   lgbese na fun mi.


4. Mo wo, mo si rerin 

   Mo tun wo, mo sokun 

   Eri ife Re si mi ni 

   Ngo toju re titi.


5. Ki tun s'edidi mo 

   Sugbon iranti ni! 

   Pe gbogbo igbese mi ni 

   Emmanuel san. Amin

English »

Update Hymn