HYMN 528

C.M.S 346 O. t.H.C 320 
C.M (FE 553)
"E ma ru eru omonikeji nyin"
 - Gal. 6:21. ALABUKUN ni fun ife 

   Ti ki oje k’a ya

   Bi ara wa jina s’ara 

   Okun wa wa l’okan.


2. Da opo Emi s‘ori wa 

   Ona t’Ola l’a nto 

   Nipa ti Jesu l’a si nrin 

   Iyin Re l'a nfi han.


3. Awa ba ma rin l‘ona Re 

   K’a ma sin m’ohun kan

   K’a ma fe ‘hun kan, bikose 

   Jesu t’a pa fun wa.


4. K'a sunmo O girigiri

   Ati si ona Re

  K‘a ma r’ore gba lodo Re 

  Ekun ore-ofe. Amin

English »

Update Hymn