HYMN 530

H.C 478 8s 4s (FE 556) 
"Ore kan mbe ti o fi ara mo mi 
ji arakunrin Io" - Owe 18:241. ENIKAN mbe t’o feran wa, 

   A! O fe wa!

   Ife re ju ti yekan lo

   A! O fe wa

   Ore aiye nko wa sile 

   B’oni dun ola le koro 

   Sugbon ore yi ko ntan ni 

   A! O fe wa!


2. lye ni fun we b’a ba mo 

   A! O fe wa!

   Ro, b’a ti je n’igbese to 

   A! O fe wa!

   Eje Re lo si fi ‘ra wa 

   Nin’aginju l’o wa wa ri 

   O si mu wa wa s’agbo Re 

   A! O fe wa!


3. Ore ododo ni Jesu

   A! O fe wa!

   O fe lati ma bukun wa 

   A! O fe wa!

  Okan wa fe gbo ohun Re 

  Okan wa fe lati sunmo 

  On na ko si ni tan wa je 

  A! O fe wa!


4. Loko Re la nri dariji 

   A! O fe wa!

  On o fe ota wa sehin 

  A! O fe wa!

  On o le ota wa sehin 

  A! O fe wa!

  On o pese bukun fun wa 

  lre l'a o ma ri titi

  On o fi mu wa lo s’Ogo 

  A! O fe wa! Amin

English »

Update Hymn