HYMN 533

C&F 562: Y.L.C 43 S.S & S 59 
(FE 559)1. IFE to fi wa emi ti eru ese npa

   O fi owo Re fa mi mora pada s'agbo 

   Angeli nfi ayo korin pelu

   awon ogun orun.

Egbe: A! ife t'o wa mi, A!

      Eje t'o ra mi

      Suru pelu ore-ofe Re

      To fa mi pada bo, wa s'agbo!


2. O w’ese mi nu kuro k‘emi 

   Le di mimo

   O so fun mi jeje pe‐lwo 

   sa je t'emi

   Ko si ohun to dun t'eyi lo

   mu alare okan yo. 

Egbe: A! ife t'o wa mi, A!...


3. Emi y’o wa si ‘hin yi, ile 

   owo mimo

   Pelu okan igbagbo, lati 

   toro bukun

   O dabi enipe ojo ngun lati

   fi iyin Re han. 

Egbe: A! ife t'o wa mi, A!...


4. Nje nigbat‘ orun ba wo 

   t’ojo oni si lo

   Ngo se’reti owuro ti yio 

   mu ayo wa!

   Titi ao fi pe mi lati bo

   sinu isimi Re.

Egbe: A! ife t'o wa mi, A!

      Eje t'o ra mi

      Suru pelu ore-ofe Re

      To fa mi pada bo, wa s'agbo! Amin

English »

Update Hymn