HYMN 535

(FE 561) PM
"Ko tun si” - Efe. 5:21. KO tun s’ore ti o dabi Jesu

   Ko tun si, Ko tun si

   Ko tun s'eni le wo banuje

   wa san

   Ko tun, Ko tun.

Egbe: Jesu mo gbogbo ijakadi 

      Y'o samona wa titi d’opin

      Ko tun s'ore ti o dabi Jesu 

      Ko tun si, ko tun si.


2. Ko tun s'ore to ga to mo bi Re 

   Ko tun si, Ko tun si

   Ko tun s’ore to ni suru bi Re 

   Ko tun si, Ko tun si.

Egbe: Jesu mo gbogbo ijakadi...


3. Ko si gba kan ti ko si lodo Re

   Ko si se, Ko si se

   Ko si sa kan ti ko ntu wa n’nu 

   Ko si se, Ko si se.

Egbe: Jesu mo gbogbo ijakadi...


4. Ko s’eni re ti Jesu ko sunmo 

   Ko ma si, Ko ma si

   Ko s’elese ti Jesu ko le gba 

   Ko ma si, Ko ma si.

Egbe: Jesu mo gbogbo ijakadi...


5. Ko s’ ebun kan to tobi to Jesu 

   Ko tun si, Ko tun si

   Ko si je le wa n'ile Re l’orun 

   Ko tun si, Ko tun si.

Egbe: Jesu mo gbogbo ijakadi 

      Y'o samona wa titi d’opin

      Ko tun s'ore ti o dabi Jesu 

      Ko tun si, ko tun si. Amen

English »

Update Hymn