HYMN 551

C.M.S 452 H.C 456 t. H.C 173 L.M (FE 578)
"Baptist won l'oruko Baba ati niti Omo
ati niti Emi Mimo" - Matt.28:191. WA Emi, Mimo sokale 

   Onibaptisi okan wa

   M’edidi majemu Re wa 

   K‘o si se eri omi yi.


2. Tu agbara nla Re jade 

   K'o o si won eje etutu 

   Ki Baba, Omo at‘ Emi

   Jo so won d'omo Olorun. Amin

English »

Update Hymn