HYMN 553

S.I 8:5 (FE 580)
Tune: Ha! Egbe mi E w’asia
“Awa ki yio beru” - Ps. 46:21. EGBE Seraf’e w’asia 

   Bo ti nfe lele

   Awa Kerub’ si ti mura 

   Awa yio segun.

Egbe: Nde Baba Aladura nde 

      Jesu lo ran O

      Awa Omo Re ti mura 

      Awa ki yio beru.


2. Wo Satan pel‘ogun re 

   Maikiel fon won ka 

   Awon Alagbara subu 

   Seraf‘ te won pa.

Egbe: Nde Baba Aladura...


3. Jesu Olugbala wipe 

   Emi fere de

   A si ayo dahun pe

   E dide asegun.

Egbe: Nde Baba Aladura...


4. Nigbati ogun ba gbona

   O pe, Ma beru

   L'o to Balogun wa Maikiel 

   Si fa da re yo.

Egbe: Nde Baba Aladura...


5. Wo Asia Jesu ti nfe

   Ohun lpe ndun

   Mose yio segun gbogbo ota 

   Lagbara Jesu.

Egbe: Nde Baba Aladura nde 

      Jesu lo ran O

      Awa Omo Re ti mura 

      Awa ki yio beru. Jesu

English »

Update Hymn