HYMN 554

C.M.S 361 H.C 5s 8s (FE 581)
“Eniti nlo Iona siwaju nyin, ninu ina 
li oru lati fi ona han nyin ati ninu 
awosanma losan" - Deut 1:331. JESU, ma to wa 

   Tit’ao fi simi

   Bi ona wa ko tile dan 

   A o tele O laifoiya

   F’owo Re to wa 

   S'ilu Baba wa.


2. B’ona ba lewu 

   B’ota sunmo wa

   Ma jek’aigbagbo m'eru wa

   Ki gbagbo on ‘reti ye

   Tor’arin ota

   L’anlo s’ile wa.


3. Gbat’ a f'e tunu 

   Ninu’ banuje

   Gbat’ idanwo titun ba de 

   Oluwa fun wa ni suru

   F’ilu ni han wa

   Ti ekun ko si.


4. Jesu, ma to wa 

   Tit' ao ti ni simi

   Amona orun, toju wa 

   Dabobo wa, to ju wa 

   Titi ao fi de 

   Ilu Baba wa. Amin

English »

Update Hymn