HYMN 56

1. KRIST‘ Jesu l'agbara 
 
   Agbara 'dariji

   Agbara ti n so ni d'aaye 

   T‘o f'iye f'elese

   Krist’ Jesu l'agbara 

   Rohin re n'bi gbogbo! 

   Gbe okan ebi re to O wa 

   Yoo f’oor’ofe gba O. 

Egbe: Krist' Jesu l'agbara 

      Agbura Olorun

      Krist' Jesu I'agbara 

      Mo jo w'okan mi fun Un 

      Krist’ Jesu l'agbara 

      Ngo gbekele E titi

      Krist' Jesu l’agbara 

      Mo ju ba, wole fun Un.


2. Krist’ Jesu l'agbara 
 
   Lati so ni d'otun

   Lati w'ese kuro l'okan 

   Lati so di pipe

   Krist’ Jesu l’agbara 

   Lati pamo d'opin 

   Ko s’eni‘t'o le ja awon 

   Agutan low Re.

Egbe: Krist' Jesu l'agbara...


3. Krist‘ Jesu l‘agbara

   Lati tu ni ninu

   Agbara lati ru gbogbo 

   Aniyan okan re

   Krist’ Jesu l‘agbara

   Lati n’o’ omije nu

   Saa f‘igboya ro m’Oluwa 

   Gboran, si gbekele E. 

Egbe: Krist' Jesu l'agbara...


4. Krist' Jesu l’agbara 

   'Gbara lati parun 

   Lati bori ota t‘o n fe 

   Gb‘ogun ti okan re 

   Krist' Jesu l'agbara 

   Lor'akete iku

   Lati f'okan re ni ‘segun 

   Lati ji o dide 

Egbe: Krist' Jesu l'agbara... Amin

English »

Update Hymn