HYMN 563

H.C 362 t.H.C 2nd Ed 
333 3.8s (FE 590)
“Oluwa mbe fun mi, emi ki o beru 
kili enia le se si mi” - Ps.118:61. NGO se foiya ojo ibi? 

   Tabi ki nma beru ota?

   Jesu papa ni odi mi.


2. B’o ti wu k’ija gbona to! 

   K'a mase gbo pe emi nsa 

   Tori Jesu l’apata mi.


3. Nko mo ‘hun t’o le de, nko mo 

   Bi nki y’o ti se wa l’aini 

   Jesu l'o mo, y’o si pese.


4. Bi mo kun f'ese at‘osi 

   Mo le sunmo Ite-anu 

   Tori jesu l’ododo mi.


5. B’adura mi ko ni lari 

   Sibe’reti mi ki o ye 

   Tori Jesu mbebe loke.


6. Aiye at’esu nde si mi

   Sugbon Olorun wa fun mi

   Jesu l’ohun gbogbo fun mi. Amin

English »

Update Hymn