HYMN 567

H.C 364 8s 7S (FE 594) 
“Ese ti enyin fi sojo be?"
 - Matt.8:261. ESE d’eru? wo, Jesu ni! 

   On tika’Re l’o ntoko

   E ta gbokun si afefe 

   Ti y’o gbe wa la ibu 

   Lo si ilu

   Bit’ olofo ye sokun.


2. B’a ko mo bit’a nlo gun si 

   Ju b’ati ngbohin re lo 

   Sugb'a ko ‘hun gbogbo sile 

   A tele ihin t’a gbo

   Pelu Jesu

   A nla arin ibu lo.


3. A ko beru igbi okun

   A ko si ka iji si

   Larin rukerudo, a mo

   P’Oluwa mbe nitosi

   Okun gba gbo

   lji sa niwaju Re. 

 
4. B'ayo wa o ti to lohun 

   lji ki ja de ibe

   Nibe l'awon ti nsota wa 

   Ko le yo wa lenu mo 

   Wahala pin

   L'ebute alafia na. Amin

English »

Update Hymn