HYMN 570

H.C. 2nd Ed 339 9s (FE 597)
"Enikan yio si je bi ibi ilumo kuro 
Ioju efufu, ati abo kuro Iowo 
iji" - Isa.32:21. JESU, Oba, ayo alare 

   Itunu onirobinuje 

   Ile alejo, agbara lai 

   Ibi isadi, Olugbala.


2. Onife nla, Alafehinti 

   Alaifia l'akoko iku

   Ona at'ere onirele

   ‘Wo li emi awon enia Re.


3. Bi mo ko se, em’o kepe O 

   Iwo ti s’ade onirele

   Bi mo sako, fi ona han mi 

   Olugbala at’ore toto.


4. Ngo jewo ore re ngo korin 

   Ibukun, ogo iyin si O

   Gbogbo ‘pa mi tit’aiye y’o je, 

   Tire Olugbala, Ore mi. Amin

English »

Update Hymn