HYMN 571

H.C 508 11s (FE 598)
"Fa mi lo si ile idurosinsin"
- Ps. 143:101. DIDAN l'opagun wa

   O ntoka s‘orun

   O nfonahan ogun,

   s‘ile won orun

   Larin aginju l’a nrin,

   l’ayo l’a ngbadura

   Pel‘ okan isokan l’a ‘m' on’

   orun pon,

Egbe: Didan I'opagun wa, 

      O ntoka s’orun

      O nfonahan ogun,

      s 'ile won orun.


2. Jesu Oluwa wa, 

   l’ese re owo 

   Pelu okan ayo 

   l’omo Re pade

   A ti fi O sile, 

   a si ti sako,

   To wa Olugbala 

   si ona toro

Egbe: Didan I'opagun wa...


3. To wa l’ojo gbogbo l’ona

   t'awa nto

   Mu wa nso s’isegun 

   l'ori ota wa

   K’Angeli Re s'asa wa 

   gb’oju orun su

   Dariji, si gba wa

   l'akoko iku.

Egbe: Didan I'opagun wa...


4. K'a le pelu awon Angel 

   l'oke,

   Lati jumo ma yin

   n'ite ife Re

   Ghat’ ajo wa ba pin, 

   isimi y’o de

   At'alafia,

   at’orin ailopin.

Egbe: Didan I'opagun wa, 

      O ntoka s’orun

      O nfonahan ogun,

      s 'ile won orun. Amin

English »

Update Hymn