HYMN 573

S. 8. 5 (FE 600)
"Sugbon eyi ti enyin ti gbe e di mu
sinsin titi emi o fi de" - Ifi.2:251. HA! egbe mi, e w’asia 

   Bi ti nfe lele

   Ogun Jesu fere de na 

   A fere segun. 

Egebe: D'odi mu, emi fere de 

       Beni Jesu nwi

       Ran dahun pada s’orun pe 

       Awa o dimu.


2. Wo opo ogun ti mbo wa, 

   Esu nko won bo

   Awon alagbara nsubu

   A fe damu tan!

Egebe: D'odi mu...


3. Wo asia Jesu ti nfe 

   Gbo ohun ipe

   A o segun gbogbo ota 

  Ni oruko Re.

Egebe: D'odi mu...


4. Ogun ngbo ‘na girigiri 

   Iranwo wa mbo 

   Balogun wa mbo wa tete 

   Egbe tujuka.

Egebe: D'odi mu, emi fere de 

       Beni Jesu nwi

       Ran dahun pada s’orun pe 

       Awa o dimu. Amin

English »

Update Hymn