HYMN 580

(FE 607) 
1. OKAN mi yo ninu Oluwa

   Tori o je lye fun mi

   Ohun re dun pupo lati gbo

   Adun ni lati r’oju Re

   Emi yo ninu Re (2ce)

   Gagbogbo l’o nfi ayo kun okan mi 

   Tori emi yo ninu Re.


2. O ti wa mi pe ki nto mo O 

   Gbati mo rin jina sagbo

   O gbe mi wa sile l‘apa Re 

   Nibiti papa tutu wa

   Emi yo ninu Re (2ce) 

   Gbagbogbo l’o nfi ayo kun okan mi 

   Tori emi yo ninu Re.


3. Ore at’anu Re yi mi ka 

   Or’ofe Re nsan bi odo 

   Emi Re nto, o si nse tunu 

   O ba mi lo sibikibi

   Emi yo ninu Re (2ce) 

   Gbagbogbo l’o nfi ayo kun okan mi 

   Tori emi yo ninu Re.


4. Emi y'o dabi Re n’ijo kan

   O s’eru wuwo mi kale 

   Titi gbana ngo j’olotito
 
   K‘emi si s’oso pade Re 

   Emi yo ninu Re (2ce) 

   Gbagbogbo l’o nfi ayo kun okan mi 

   Tori emi yo ninu Re. Amin


English »

Update Hymn