HYMN 590

C.M.S,.391 H.C 351 L.M (FE 616) 
“Bi enikan ba nfe lati ma to mi lehin, 
ki o ara re, ki o si ma gbe agbelebu 
re lojo gbogbo ki o si ma to mi lehin”
- Luku.9:231. GB'AGBELEBU re ni Kristi wi 

   B'o ba fe s’omo ehin Mi

   Se ‘ra re ko aiye sile

   Si ma fi ‘rele tele mi.


2. Gb’agbelebu re, ma je ki 

   Iwuwo re fo o laiya

   Ipa mi y‘o gb’emi re ro 

   Y‘o m’okan at’apa re le.


3. Gb'agbelebu re ma tiju 

   Ma je k’okan were re ko 

   Oluwa ru agbelebu

   Lati gba o lowo iku.


4. Gb’agbelebu re, ma tele

   Mase gbe sile tit'iku

   Enit' o ru agbelebu

   L’o le reti lati d’ade.


5. 'Wo Olorun Metalokan 

   L'a o ma yin titi aiye 

   Fun wa k’a le ri n’ile wa 

   Ayo orun ti ko lopin. Amin

English »

Update Hymn